Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 20:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Jehoṣafati ati awọn enia rẹ̀ de lati kó ikogun wọn, nwọn ri lara wọn ọ̀pọlọpọ ọrọ̀, ati okú, ati ohun-elo iyebiye, nwọn si kójọ fun ara wọn, jù eyiti nwọn le kó lọ: nwọn si kó ikogun wọn jọ ni ijọ mẹta, nitoriti o sa papọ̀ju.

Ka pipe ipin 2. Kro 20

Wo 2. Kro 20:25 ni o tọ