Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 16:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọdun kẹrindilogoji ijọba Asa, Baaṣa, ọba Israeli, gòke wá si Juda, o si kọ́ Rama, nitori ki o má ba jẹ ki ẹnikan ki o jade, tabi ki o wọle tọ̀ Asa, ọba Juda lọ.

Ka pipe ipin 2. Kro 16

Wo 2. Kro 16:1 ni o tọ