Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 15:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kó gbogbo Juda ati Benjamini jọ, ati awọn alejo ti o pẹlu wọn lati inu Efraimu ati Manasse, ati lati inu Simeoni wá: nitori ti nwọn ya li ọ̀pọlọpọ sọdọ rẹ̀ lati inu Israeli wá, nigbati nwọn ri pe, Oluwa Ọlọrun rẹ̀ wà pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 15

Wo 2. Kro 15:9 ni o tọ