Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 15:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Asa gbọ́ ọ̀rọ wọnyi, ati asọtẹlẹ Odedi woli, o mu ara le, o si mu awọn ohun irira kuro lati inu gbo-gbo ilẹ Juda ati Benjamini, ati lati inu ilu ti o ti gbà lati oke Efraimu, o si tun pẹpẹ Oluwa ṣe, ti o wà niwaju iloro Oluwa.

Ka pipe ipin 2. Kro 15

Wo 2. Kro 15:8 ni o tọ