Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 10:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati gbogbo Israeli ri pe, ọba kọ̀ lati fetisi ti wọn, awọn enia na da ọba lohùn, wipe, Ipin kili a ni ninu Dafidi? awa kò si ni ini kan ninu ọmọ Jesse: Israeli, olukuluku sinu agọ rẹ̀: nisisiyi Dafidi, mã bojuto ile rẹ. Bẹ̃ni gbogbo Israeli lọ sinu agọ wọn,

Ka pipe ipin 2. Kro 10

Wo 2. Kro 10:16 ni o tọ