Samueli si mu Saulu ati iranṣẹ rẹ̀, o si mu wọn wọ inu gbàngàn, o si fun wọn ni ijoko lãrin awọn agbagba ninu awọn ti a pè, nwọn si to ọgbọ̀n enia.