Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 9:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si ni ọmọkunrin kan, ẹniti a npè ni Saulu, ọdọmọkunrin ti o yàn ti o si ṣe arẹwa, kò si si ẹniti o dara ju u lọ ninu gbogbo awọn ọmọ Israeli: lati ejika rẹ̀ lọ si oke, o ga jù gbogbo awọn enia na lọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 9

Wo 1. Sam 9:2 ni o tọ