Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NJẸ ọkunrin kan ara Benjamini si wà, a ma pe orukọ rẹ̀ ni Kiṣi, ọmọ Abeli, ọmọ Sesori, ọmọ Bekorati, ọmọ Afia, ara Benjamini ọkunrin alagbara.

Ka pipe ipin 1. Sam 9

Wo 1. Sam 9:1 ni o tọ