Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 30:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si bi i lere pe, Ọmọ tani iwọ iṣe? ati nibo ni iwọ ti wá? On si wipe, ọmọ ara Egipti li emi iṣe, ọmọ-ọdọ ọkunrin kan ara Amaleki; oluwa mi si fi mi silẹ, nitoripe lati ijọ mẹta li emi ti ṣe aisan.

Ka pipe ipin 1. Sam 30

Wo 1. Sam 30:13 ni o tọ