Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 30:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si bùn u li akara eso ọpọtọ ati ṣiri ajara gbigbẹ meji: nigbati o si jẹ ẹ tan, ẹmi rẹ̀ si sọji: nitoripe ko jẹ onjẹ, bẹ̃ni kò si mu omi ni ijọ mẹta li ọsan, ati li oru.

Ka pipe ipin 1. Sam 30

Wo 1. Sam 30:12 ni o tọ