Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 28:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli sì ti kú, gbogbo Israeli si sọkun rẹ̀, nwọn si sin i ni Rama ni ilu rẹ̀. Saulu si ti mu awọn abokusọ̀rọ-ọkunrin, ati awọn abokusọ̀rọ-obinrin kuro ni ilẹ na.

Ka pipe ipin 1. Sam 28

Wo 1. Sam 28:3 ni o tọ