Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 28:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wi fun Akiṣi pe, Nitotọ iwọ o si mọ̀ ohun ti iranṣẹ rẹ le ṣe. Akiṣi si wi fun Dafidi pe, Nitorina li emi o ṣe fi iwọ ṣe oluṣọ ori mi ni gbogbo ọjọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 28

Wo 1. Sam 28:2 ni o tọ