Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 26:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abiṣai si wi fun Dafidi pe, Ọlọrun ti fi ọta rẹ le ọ lọwọ loni: njẹ, emi bẹ ọ, sa jẹ ki emi ki o fi ọ̀kọ gun u mọlẹ lẹ̃kan, emi ki yio gun u lẹ̃meji.

Ka pipe ipin 1. Sam 26

Wo 1. Sam 26:8 ni o tọ