Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 25:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abigaili si yara, o dide, o si gun kẹtẹkẹtẹ, awọn iranṣẹbinrin rẹ̀ marun si tẹle e lẹhin; on si tẹle awọn iranṣẹ Dafidi, o si wa di aya rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:42 ni o tọ