Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 23:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si ngbe ni aginju, nibiti o ti sa pamọ si, o si ngbe nibi oke-nla kan li aginju Sifi. Saulu si nwá a lojojumọ, ṣugbọn Ọlọrun ko fi le e lọwọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 23

Wo 1. Sam 23:14 ni o tọ