Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 21:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si da alufa na lohùn, o si wi fun u pe, Nitotọ a ti pa ara wa mọ kuro lọdọ obinrin lati iwọn ijọ mẹta wá, ti emi ti jade; gbogbo nkan awọn ọmọkunrin na li o mọ́, ati akara na si wa dabi akara miran, ye e pãpã nigbati o jẹ pe omiran wà ti a yà si mimọ́ loni ninu ohun elo na.

Ka pipe ipin 1. Sam 21

Wo 1. Sam 21:5 ni o tọ