Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 18:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si dide, o lọ, on ati awọn ọmọkunrin rẹ̀, o si pa igba ọmọkunrin ninu awọn Filistini; Dafidi si mu ẹfa abẹ wọn wá, nwọn si kà wọn pe fun ọba, ki on ki o le jẹ ana ọba. Saulu si fi Mikali ọmọ rẹ obinrin fun u li aya.

Ka pipe ipin 1. Sam 18

Wo 1. Sam 18:27 ni o tọ