Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 17:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wipe, Oluwa ti o gbà mi lọwọ́ kiniun ati lọwọ́ amọtẹkun, on na ni yio gbà mi lọwọ́ Filistini yi. Saulu si wi fun Dafidi pe, Lọ, Oluwa yio si pẹlu rẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:37 ni o tọ