Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti o rù ihamọra rẹ̀ na wi fun u pe, Ṣe gbogbo eyi ti o mbẹ li ọkàn rẹ: ṣe bi o ti tọ́ li ọkàn rẹ; wõ, emi wà pẹlu rẹ gẹgẹ bi ti ọkàn rẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:7 ni o tọ