Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jonatani wi fun ọdọmọdekunrin ti o rù ihamọra rẹ̀ pe, Wá, si jẹ ki a lọ si budo-ogun awọn alaikọla yi: bọya Oluwa yio ṣiṣẹ fun wa: nitoripe kò si idiwọ fun Oluwa lati fi pipọ tabi diẹ gba là.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:6 ni o tọ