Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu wipe, Ẹ jẹ ki a sọkalẹ tọ̀ awọn Filistini lọ li oru, ki a ba wọn ja titi di imọlẹ owurọ̀, ẹ má jẹ ki a fi ọkunrin kan silẹ ninu wọn. Nwọn si wipe, Ṣe gbogbo eyi ti o tọ loju rẹ. Nigbana ni alufa ni si wipe, Ẹ jẹ ki a sunmọ ihinyi si Ọlọrun.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:36 ni o tọ