Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni nwọn wi fun Saulu pe, kiye si i, awọn enia na dẹ̀ṣẹ si Oluwa, li eyi ti nwọn jẹ ẹjẹ. On si wipe, Ẹnyin ṣẹ̀ kọja: yi okuta nla fun mi wá loni.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:33 ni o tọ