Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jonatani wipe, baba mi yọ ilu li ẹnu, sa wo bi oju mi ti walẹ, nitori ti emi tọ diẹ wò ninu oyin yi.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:29 ni o tọ