Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li ọkan ninu awọn enia na dahùn wipe, baba rẹ ti fi ifibu kilọ fun awọn enia na, pe, ifibu li ọkunrin na ti o jẹ onjẹ li oni. Arẹ̀ si mu awọn enia na.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:28 ni o tọ