Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 12:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si ran Jerubbaali, ati Bedani, ati Jefta ati Samueli, nwọn si gbà nyin lọwọ́ awọn ọta nyin niha gbogbo, ẹnyin si joko li alafia.

Ka pipe ipin 1. Sam 12

Wo 1. Sam 12:11 ni o tọ