Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 11:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo enia na si lọ si Gilgali; nibẹ ni nwọn gbe fi Saulu jọba niwaju Oluwa ni Gilgali: nibẹ ni nwọn gbe ru ẹbọ irẹpọ̀ niwaju Oluwa; nibẹ ni Saulu ati gbogbo awọn ọkunrin Israeli si yọ ayọ̀ nlanla.

Ka pipe ipin 1. Sam 11

Wo 1. Sam 11:15 ni o tọ