Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 28:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ìwọn ọpa fitila wura, ati fitila wura wọn, nipa ìwọn fun olukuluku ọpa fitila ati ti fitila rẹ̀: ati niti ọpa fitila fadakà nipa ìwọn, ti olukuluku ọpa fitila ati ti fitila rẹ̀, gẹgẹ bi ìlo olukuluku ọpa fitila.

Ka pipe ipin 1. Kro 28

Wo 1. Kro 28:15 ni o tọ