Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 22:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, a o bi ọmọ kan fun ọ, ẹniti yio ṣe enia isimi; emi o si fun u ni isimi lọdọ gbogbo awọn ọta rẹ̀ yika kiri: nitori orukọ rẹ̀ yio ma jẹ Solomoni, emi o si fi alafia ati idakẹjẹ fun Israeli li ọjọ aiye rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Kro 22

Wo 1. Kro 22:9 ni o tọ