Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 22:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ọ̀rọ Oluwa tọ̀ mi wá, wipe, Iwọ ti ta ẹ̀jẹ silẹ li ọ̀pọlọpọ, iwọ si ti ja ogun nlanla: iwọ kò gbọdọ kọ́ ile fun orukọ mi, nitoriti iwọ ta ẹ̀jẹ pipọ̀ silẹ niwaju mi.

Ka pipe ipin 1. Kro 22

Wo 1. Kro 22:8 ni o tọ