Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 22:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wipe, Solomoni ọmọ mi, ọdọmọde ni, o si rọ̀, ile ti a o si kọ́ fun Oluwa, a o si ṣe e tobi jọjọ, fun okiki ati ogo ka gbogbo ilẹ: nitorina emi o pese silẹ fun u. Bẹ̃ni Dafidi si pese silẹ lọ̀pọlọpọ, ki o to kú.

Ka pipe ipin 1. Kro 22

Wo 1. Kro 22:5 ni o tọ