Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 22:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi ẹ fi aiya nyin ati ọkàn nyin si atiwá Oluwa Ọlọrun nyin; nitorina dide ki ẹ si kọ́ ibi mimọ́ Oluwa Ọlọrun, lati mu apoti ẹri ti majẹmu Oluwa wọ̀ inu rẹ̀, ati ohun èlo mimọ́ Ọlọrun, sinu ile na ti a o kọ́ fun orukọ Oluwa.

Ka pipe ipin 1. Kro 22

Wo 1. Kro 22:19 ni o tọ