Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 20:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si gbà ade ọba wọn kuro lori rẹ̀, o si ri i pe o wọ̀n talenti wura kan, okuta iyebiye si wà lara rẹ̀; a si fi de Dafidi li ori: o si kó ikogun pipọpipọ lati inu ilu na wá.

Ka pipe ipin 1. Kro 20

Wo 1. Kro 20:2 ni o tọ