Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 20:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O SI ṣe lẹhin igbati ọdun yipo, li akokò ti awọn ọba lọ si ogun; Joabu si gbé agbara ogun jade, o si ba ilu awọn ọmọ Ammoni jẹ, nwọn si wá, nwọn si do tì Rabba. Ṣugbọn Dafidi duro ni Jerusalemu. Joabu si kọlù Rabba o si pa a run.

Ka pipe ipin 1. Kro 20

Wo 1. Kro 20:1 ni o tọ