Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 15:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wọ̀ aṣọ igunwa ọ̀gbọ daradara, ati gbogbo awọn ọmọ Lefi ti nrù apoti ẹri na, ati awọn akọrin, ati Kenaniah olori orin pẹlu awọn akọrin: efodu ọ̀gbọ si wà lara Dafidi.

Ka pipe ipin 1. Kro 15

Wo 1. Kro 15:27 ni o tọ