Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 10:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si bọ́ ọ li aṣọ, nwọn si gbé ori rẹ̀ ati ihamọra rẹ̀, nwọn si ranṣẹ si awọn ara Filistia yika, lati mu ihin lọ irò fun awọn ere wọn, ati fun awọn enia.

Ka pipe ipin 1. Kro 10

Wo 1. Kro 10:9 ni o tọ