Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 10:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ni ijọ keji, nigbati awọn ara Filistia de lati wá bọ́ awọn okú li aṣọ, nwọn si ri Saulu pẹlu, ati awọn ọmọ rẹ̀ pe; nwọn ṣubu li òke Gilboa.

Ka pipe ipin 1. Kro 10

Wo 1. Kro 10:8 ni o tọ