Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi enia rẹ ba jade lọ si ogun si ọtá wọn, li ọ̀na ti iwọ o rán wọn, bi nwọn ba si gbadura si Oluwa siha ilu ti iwọ ti yàn, ati siha ile ti mo kọ́ fun orukọ rẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:44 ni o tọ