Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ gbọ́ li ọrun, ibùgbe rẹ, ki o si ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti alejò na yio ke pè ọ si: ki gbogbo aiye ki o lè mọ̀ orukọ rẹ, ki nwọn ki o lè mã bẹ̀ru rẹ, gẹgẹ bi Israeli, enia rẹ, ki nwọn ki o si lè mọ̀ pe: orukọ rẹ li a fi npè ile yi ti mo kọ́.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:43 ni o tọ