Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a ba lù Israeli, enia rẹ bòlẹ niwaju awọn ọ̀ta, nitoriti nwọn dẹṣẹ si ọ, ti nwọn ba si yipada si ọ, ti nwọn si jẹwọ orukọ rẹ, ti nwọn si gbadura, ti nwọn si bẹ̀bẹ lọdọ rẹ ni ile yi:

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:33 ni o tọ