Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki oju rẹ lè ṣi si ile yi li ọsan ati li oru, ani si ibi ti iwọ ti wipe: Orukọ mi yio wà nibẹ: ki iwọ ki o lè tẹtisilẹ si adura ti iranṣẹ rẹ yio gbà si ibi yi.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:29 ni o tọ