Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 3:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo Israeli si gbọ́ idajọ ti ọba ṣe; nwọn si bẹ̀ru niwaju ọba: nitoriti nwọn ri i pe, ọgbọ́n Ọlọrun wà ninu rẹ̀, lati ṣe idajọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 3

Wo 1. A. Ọba 3:28 ni o tọ