Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni si jí; si wò o, alá ni. On si wá si Jerusalemu, o si duro niwaju apoti majẹmu Oluwa, o si rubọ ọrẹ sisun, o si ru ẹbọ-alafia, o si se àse fun gbogbo awọn iranṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 3

Wo 1. A. Ọba 3:15 ni o tọ