Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 21:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahabu si wi fun Elijah pe, Iwọ ri mi, Iwọ ọta mi? O si dahùn wipe, Emi ri ọ; nitoriti iwọ ti tà ara rẹ lati ṣiṣẹ buburu niwaju Oluwa.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 21

Wo 1. A. Ọba 21:20 ni o tọ