Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 13:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin nkan yi, Jeroboamu kò pada kuro ninu ọ̀na ibi rẹ̀, ṣugbọn o tun mu ninu awọn enia ṣe alufa ibi giga wọnni: ẹnikẹni ti o ba fẹ, a yà a sọtọ̀ on a si di alufa ibi giga wọnni.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:33 ni o tọ