Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 13:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kigbe si pẹpẹ na nipa ọ̀rọ Oluwa, o si wipe, Pẹpẹ! pẹpẹ! bayi li Oluwa wi, Kiyesi i, a o bi ọmọ kan ni ile Dafidi, Josiah li orukọ rẹ̀; lori rẹ ni yio si fi awọn alufa ibi giga wọnni ti nfi turari jona lori rẹ rubọ, a o si sun egungun enia lori rẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:2 ni o tọ