Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 13:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

SI kiyesi i, enia Ọlọrun kan lati Juda wá si Beteli nipa ọ̀rọ Oluwa: Jeroboamu duro lẹba pẹpẹ lati fi turari jona.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:1 ni o tọ