Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 8:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn rubọ ẹran ninu ẹbọ ẹran mi, nwọn si jẹ ẹ; Oluwa kò tẹwọgbà wọn; nisisiyi ni yio ránti ìwa-buburu wọn, yio si bẹ̀ ẹ̀ṣẹ wọn wò: nwọn o padà lọ si Egipti.

Ka pipe ipin Hos 8

Wo Hos 8:13 ni o tọ