Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 3:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhìn na awọn ọmọ Israeli yio padà, nwọn o si wá Oluwa Ọlọrun wọn, ati Dafidi ọba wọn; nwọn o si bẹ̀ru Oluwa, ati ore rẹ̀ li ọjọ ikẹhìn.

Ka pipe ipin Hos 3

Wo Hos 3:5 ni o tọ