Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 3:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ọjọ pupọ̀ li awọn ọmọ Israeli yio gbe li aini ọba, ati li aini olori, ati li aini ẹbọ, li aini ere, ati li aini awòaiyà, ati li aini tẹrafimu.

Ka pipe ipin Hos 3

Wo Hos 3:4 ni o tọ