Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hag 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hagai si wipe, Bi ẹnikan ti o ba jẹ alaimọ́ nipa okú ba fi ara kan ọkan ninu wọnyi, yio ha jẹ alaimọ́? Awọn alufa si dahùn wipe, Yio jẹ alaimọ́.

Ka pipe ipin Hag 2

Wo Hag 2:13 ni o tọ